Wt/yo/Bàbá

< Wt‎ | yo
Wt > yo > Bàbá

Yorùbá edit

Ọ̀rọ̀ orúkọ edit

Bàbá jẹ́ ọ̀rọ̀-orúkọ [1] ẹni tí a fi ń pe ẹni tí ó jẹ́ akọ tàbí ọkùnrin

Bàbá jẹ́ ọkùnrin tí ó ń gbé tàbí tí ó ma ń fẹ́ obìnrin níṣu-lọ́kà tí ó sì tún ma ń jẹ́ ọkọ fún abo nígbà tí ó sì tún jẹ́ bàbá fún awọn ọmọ tí obìnrin bá bí fún wọn. Àpẹẹrẹ: Orúkọ Bàbá Adéfowópè

Ní èdè míràn edit

Èdè Gẹ̀ẹ́sì edit

Template:Wt/yo/reflist

  1. Template:Wt/yo/cite web