Wt/yo/abo

< Wt‎ | yo
Wt > yo > abo

Yorùbá edit

Ọ̀rọ̀ orúkọ edit

Abo jẹ́ ọ̀rọ̀-orúkọ [1] fún ohun abẹ̀mí bí ọmọ ènìyàn ẹranko kòkòrò tabí ohun aláìlẹ́mú tí ó ní àwòmọ́ ìṣesí obìnrin tí ó lè lóyún, tọ́ ọmọ, tabí tí ó lè gba ìbáṣepọ̀ alààyè láti ọ̀dọ̀ akọ tàbí ọkùnrin.


Àpẹẹrẹ: Orúkọ Ìyá Abo ni adìyẹ tí mo rà wálé. Ewúrẹ́ mi bí ọmọ méjì tí wọ́n jẹ́ abo

Ní èdè míràn edit

Èdè Gẹ̀ẹ́sì edit

Àwọn ìtọ́kasí edit

Template:Wt/yo/reflist

  1. Template:Wt/yo/cite web