Wt/yo/Ojúewé Àkọ́kọ́

< Wt | yo
Wt > yo > Ojúewé Àkọ́kọ́


Wiktionary, Ìwé atúmọ̀ ọ̀rọ̀ ọ̀fẹ́ l'édè Yorùbá

Iye àwọn ọ̀rọ̀ tí ó wà : 72 láti bí ẹgbẹ̀rún mẹrin èdè

Ṣe àwárí: gbogbo èdèÀwoṇ àkọ́lé lọríṣiríṣiỌ̀rọ̀ àrìnàkòÀwọn àfikún tuntun Àwọn atọ́kaÀgékụ́rúÌwé ìmọ̀ ThesarusÀwọn ọ̀rọ̀ tí ó bára muÀwọn ọ̀rọ̀ tí ó máa ń sábà jéyọÌwé ọ̀rọ̀ tí kò parí

 


 
Ẹkáàbọ̀ sí iwé ìwọ̀ òfẹ́ ti èdè-yorùbá, tí a ti ń fọwọ́ sowọ́pò ṣàgbéjáde ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́ ní oríṣiríṣi èdè. À ń ṣe ìtumọ̀ àti àpèjúwe àwọn ọ̀rọ̀ ní oríṣiríṣi èdè sí èdè Yorùbá.
Ìwé ìtumọ̀ Wikṣọ́nárì yí ti gbòòrò àti pé a tún ní Ìwé ìmọ̀ tí ó ń ṣe ìtumọ̀ àwọ òrọ̀ tí wọ́ ní ìtumọ̀ tí ó jọra
Wikṣọ́nárì jẹ́ wiki, tí ó túmọ̀ sí wípé ẹnikẹ́ni ló lè ṣàtúnṣe, tí ó sì wà fún lílò látàrí Creative Commons Attribution-ShareAlike 4.0 International License àti t GNU Free Documentation License. Kí ẹ tó báwa dá síi, ẹ kọ́kọ́ ka àwọn ojú ewé tí a pèsè fún ìrànwọ̣́, kí ẹ sì mọ̀ dájú wípé ó yàtọ̀ sí àwọn wiki tí ó kù. Ní pàápàá jùlọ, a ní í a ṣe fẹ́ jẹ́ kí àwọ ìtumọ̀ rí àti ìlànà àfikún. Kẹ́kọ̀ọ́ bí a ṣe lè bẹ̀rẹ̀ ojú ewé tuntun, bí a ṣe lè ṣe àtunṣe sí ojú ewé, ṣàyẹ̀wò ní ojú ewé àyèwò kí ẹ sì wo Ibùdó àwùjọ wa kí ẹ lè wo bí ẹ ṣe lè kópa nínu ìdàgbà sókè Wikṣọ́nárì Yorùbá.

Behind the scenes

Ibùdó àwùjọ wa

Ojú ewé tí ó ní gbogbo oun tí ẹ fẹ́ mọ̀ nípa wikiṣọ́nárì wà ní A page containing everything you wanted to know about Wiktionary.

Yàrá ìjíròrò

Àwọn ojú ewé ìjíròrò Wikṣọ́nárì àti àwọn ọ̀rọ̀ tí ó wà nínú rẹ̀ .
Àwọn oun tí ẹ lè ṣeÌrànlọ́wọ́Ìtọ́sọ́nàn